MyLyricsFinder

Oro

BBO

Lyrics

Ahaha Ahahahahaahah Ahahahahahahahaha Ahahahahahahahaha hahaha Is a Godly sound o Is a sound of God ooooo Ahahahahahahahaha Oro ni e ah Oro tin gbe Oro mi Oro ni e Oro to da aye ati orun Oro ni e ah Oro tin gbe Oro mi Oro ni e Oro to da aye ati orun Oro ni e ah Oro tin gbe Oro mi Oro ni e Oro to da aye ati orun Arole ni Lazaru ogboun o Kilo gbo to fi ji dide Oro lo gbo Okun pupa o gboun o Kilo gbo to fi pi ya o Oro lo gbo Inu Sara gboun o Kilo gbo to fi gbo mo Dani Oro lo gbo Goliath o gboun o Kilo gbo to fi wo lule Oro lo gbo O gbo mo to e wa Loruko olorun Eni ti iwo pe ni ja ooooo Oro ni e ah Oro tin gbe Oro mi Oro ni e Oro to da aye ati orun Oro ni e Oro to da aye ati orun Olorun to po ni IPA ati agbara Olorun alanu, soro so Ori aye mi oluwa Kaye mi ni itumo si o Soro so Ori aye omo mi Olorun alanu olorun to po ni ipa ati agbara soro so Ori aye mi Ode soro so ri aye omo mi o Emi mo pa agbara wa ninu Oro re Ntoba so Beni, your word is yes and amen Ahah