Lyrics Timed, click a line to jump
Ẹ jẹ ká catch cruise
Ẹ wa fẹ thirty two
Iṣẹ Ọlọrun adìtú
Àwọn kan carry do
Life na roller coaster
Mo ṣe n rọra jó Makosa
Pari òwe yìí
Àyé o le, fún ẹni tó mọ way
Jẹleosinmi kidergattern
Ki irẹsi tó jinmi, pe Hilda Baci
I'm dulling never (Ayayayaya)
Àbí ọ̀nà Ìsẹ́yìn lẹ gba? (You are on your own)
Ọyọ ma lẹ wà (Abi Bauchi)
Tafa Balewa
Ko pọ, kó dùn, ko pẹ
Ìyá, ìyá takùn walẹ
Ka rowo ṣe fuja ko plenty
Owó ni o wá, fi ija lẹ
Aroye ò gbowó ní bank
Kò saye fún n'gbàtí n'gbàtí
Kére o
Atara àtẹbí
Ẹ pin ko kárí Parle G
Is causing pandemic
Kọkọrọ alátẹ toun tàtẹ ni
Now I put everyone for the mood
Wọn n jẹ d'Agarawu
O ṣènìyàn, Alamu
Ọrẹ wá Aina Òrosùn
Ṣo mọ pe pay day kò mọjọ, kò mọṣù
Wọn a jó dẹndẹ
Agba wòlíì ṣí pẹpẹ
Ẹ jẹ ká catch cruise
Ẹ wa fẹ thirty two
Iṣẹ Ọlọrun adìtú
Àwọn kan carry do
Life na roller coaster (Roller coaster)
Mo ṣe n rọra jó Makosa
Pari òwe yìí (Pari òwe yìí)
Àyé o le (Àyé o le), fún ẹni tó mọ way
Jẹleosinmi kidergattern
Ki irẹsi tó jinmi, pe Hilda Baci
I'm dulling never
Àbí ọ'nà Ìsẹyìn lẹ gba?
Ọyọ' ma lẹ wà (Abi Bauchi)
Tafa Balewa
Bọbọ Aláṣàkaṣà
Now I put everyone for the mood
Wọ n n jẹ d'Agarawu
O ṣènìyàn, Alamu
Can't get it out of your head? Play “32” yourself.